Olórí orílẹ̀-èdè

Àdàkọ:Politics sidebar Olórí orílẹ̀-èdè ni ẹni aráàlú kan tí óún dúró fún orílẹ̀ ìjọba kan lábẹ́ àṣẹ ní ìṣọ̀kan àti lábẹ́ òfin rẹ̀. Bí irú ìjọba àti ìpín àwọn agbára ìjọba orílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan bá ṣe rí, olórí orílẹ̀-èdè le jẹ́ fún oyè lásán tàbí lẹ́ẹ̀kannáà bíi olórí ìjọba àti ìṣẹ́ míràn.


Ìtọ́kasí

  1. Foakes, pp. 110–11 " being an embodiment of the State itself or representatitve of its international persona."