Coordinates: 46°14′N 06°03′E / 46.233°N 6.050°E
LHC experiments | |
---|---|
ATLAS | A Toroidal LHC Apparatus |
CMS | Compact Muon Solenoid |
LHCb | LHC-beauty |
ALICE | A Large Ion Collider Experiment |
TOTEM | Total Cross Section, Elastic Scattering and Diffraction Dissociation |
LHCf | LHC-forward |
MoEDAL | Monopole and Exotics Detector At the LHC |
LHC preaccelerators | |
p and Pb | Linear accelerators for protons (Linac 2) and Lead (Linac 3) |
(not marked) | Proton Synchrotron Booster |
PS | Proton Synchrotron |
SPS | Super Proton Synchrotron |
Ẹ̀rọ Ìmúsáré Hádrónì Gbàngbà tabi Large Hadron Collider (LHC) ni ero imusare eruku pelu okun totobijulo ati togajulo lagbaye. Ó jẹ́ kíkọ́sókè látọwọ́ CERN láti ọdún 1998 dé 2008, pẹ̀lú èrò láti gba àwọn aṣefísíksì láyè láti ṣe àdánwò ìsọtẹ́lẹ̀ àwọn orísi àròjinlẹ̀ físíksì eruku àti físíksì olókun-gíga, àti àgàgà láti wá bọ́yá bósónì Higgs wà lóòótọ́ àti orísirísi àwọn eruku tuntun tí àjọbáramu adárajùlọ ṣe àsọtẹ́lẹ̀. Ìrètí ni pé LHC yíò wá ìdáhùn is expected to address some of the ọ̀pọ̀ àwọn ìbérè inú físíksì, nípa èyí láti mú ìlọsíwájú bá òye àwọn òfin àdánidá jínjnlẹ̀. Ó ní ẹ̀rọ ìwárí mẹ́fà tí ìkọ̀ọ̀kan wà fún ìwàdìí ohun pàtó kan.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |