Aretha Franklin | |
---|---|
Franklin in 1968 | |
Ọjọ́ìbí | Aretha Louise Franklin Oṣù Kẹta 25, 1942 Memphis, Tennessee, U.S. |
Aláìsí | August 16, 2018 Detroit, Michigan, U.S. | (ọmọ ọdún 76)
Resting place | Woodlawn Cemetery Detroit, Michigan |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1956 – 2018 |
Ọmọ ìlú | Detroit, Michigan |
Olólùfẹ́ |
|
Àwọn ọmọ | 4 |
Parent(s) | |
Àwọn olùbátan |
|
Awards | see, list |
Musical career | |
Irú orin | |
Instruments |
|
Labels | |
Website | |
Signature | |
Aretha Louise Franklin (March 25, 1942 – August 16, 2018) je akorin, akowe-orin, osere, ateduuru, ati alakitiyan eto araalu ara Amerika. Franklin bere si ni korin lati kekere ninu egbe akorin gospel ni ijo New Bethel Baptist Church ni Detroit, Michigan, nibi ti baba re C. L. Franklin ti je oluso-agutan. Nigba to di omo odun 18, o bere si ni korin to gbode. Awon orin re to gbajumo bi "Respect", "Chain of Fools", "Think", "(You Make Me Feel Like) A Natural Woman", "I Never Loved a Man (The Way I Love You)", ati "I Say a Little Prayer", so di akorin agba lagbaye, eyi to je ki o gbajumo bi Queen of Soul.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |