Sam Smith | |
---|---|
Smith performing at the 2015 Lollapalooza | |
Ọjọ́ìbí | Samuel Frederick Smith 19 Oṣù Kàrún 1992 London, England |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2008–present |
Awards | Full list |
Musical career | |
Irú orin | |
Instruments |
|
Labels | |
Website | samsmithworld.com |
Samuel Frederick Smith (tí a bí ní 19 May 1992) jẹ́ akọrin àti aṣẹ̀dá orin ọmọ orílè-èdè England. Lẹ́yìn tí ó di olókìkí ní oṣù kẹwàá ọdún 2012 nípasẹ̀ ìṣàfihàn rẹ̀ nínú orin àdákọ tí àkọ́lé rè ń jẹ́ " Latch ", èyí tó ṣipò kọkànlá lórí atọ́ka Singles UK. Wọ́n sì padà ṣàfihàn orin "Naughty Boy" tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "La La La" tó ṣịpò kìíní lóṣù karùn-ún, ọdún 2013. Ní oṣù kejìlá ọdún 2013, wọ́n yan Smith fún àmì-ẹ̀yẹ Brit Critics Choice Award, ti ọdún 2014, ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ méjèèjì.